Gospel singer and writer , after releasing a great song last month, blesses the air wave with a new song tited Iwo Ni(Its You).
The song elaborate the efficasy of Our God as the most reliable.
God is not man and can never fail you in time of need.
Click link below to listen to this song
Song Lyrics
Intro: instrumentalist
Chrous: Iwo ni ko se lo mi ran to le ran mi lowo Iwo ni
Call: ee Iwo ni oo
Chrous: Iwo ni ko se lo mi ran to le ran mi lowo Iwo ni (2x)
Vocal 1: Ore mi ma se gbo kan le eniyan, eniyan ase ileri wa fi tan e wa sope ma ra ile fun e ma ra moto fun e gbogbo nkan to ba fe ni ma se fun e sugbon won ti gba gbe pe olorun nbe ohun ni kan lole se eleri to de ma a mu se olorun lo le lo le ran ni lowo oti ran mi lowo ase tire ee
Chrous: Iwo ni ko se lo mi ran to le ran mi lowo Iwo ni (2x)
Vocal 2: Emi yo gbe oju mi so ori oke won ni, nibo ni Iranlowo mi yo wa tiwa Iran lowo mi yio ton wo oluwa wa, oluwa mi to da Orun ohun aye lo le ran mi lowo ohun ni Iwo ni o
Chrous: Iwo ni ko se lo mi ran to le ran mi lowo Iwo ni (2x)
Call: Iwo ni Iwo ni Iwo ni o Iwo ni o
Res: tole ran mi lowo ewo ni
Call: Iwo ni Jehovah provider
Res: tole ran mi lowo
Call: Asoro mata see to se ileri tosi mu se
Res: tole ran mi lowo ni
The End